2 Kíróníkà 34:18 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Ṣáfánì akọ̀wé tún sọ fún ọba pé: “Ìwé kan wà tí àlùfáà Hilikáyà fún mi.”+ Ṣáfánì sì bẹ̀rẹ̀ sí í kà á níwájú ọba.+
18 Ṣáfánì akọ̀wé tún sọ fún ọba pé: “Ìwé kan wà tí àlùfáà Hilikáyà fún mi.”+ Ṣáfánì sì bẹ̀rẹ̀ sí í kà á níwájú ọba.+