Léfítíkù 19:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ jẹ ohunkóhun tòun ti ẹ̀jẹ̀ rẹ̀.+ “‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ woṣẹ́, ẹ ò sì gbọ́dọ̀ pidán.+ Ìṣe 19:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ní tòótọ́, ọ̀pọ̀ lára àwọn tó ń pidán kó àwọn ìwé wọn jọ, wọ́n sì dáná sun wọ́n níwájú gbogbo èèyàn.+ Wọ́n ṣírò iye tó jẹ́, wọ́n sì rí i pé ó tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta (50,000) ẹyọ fàdákà.
19 Ní tòótọ́, ọ̀pọ̀ lára àwọn tó ń pidán kó àwọn ìwé wọn jọ, wọ́n sì dáná sun wọ́n níwájú gbogbo èèyàn.+ Wọ́n ṣírò iye tó jẹ́, wọ́n sì rí i pé ó tó ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta (50,000) ẹyọ fàdákà.