-
Sáàmù 26:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Màá jẹ́ kí ọwọ́ mi mọ́,
Màá sì rìn yí ká pẹpẹ rẹ, Jèhófà,
-
Mátíù 27:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Nígbà tó rí i pé òun ò rí nǹkan kan ṣe sí i, àmọ́ tí ariwo ń sọ, Pílátù bu omi, ó sì wẹ ọwọ́ rẹ̀ níwájú àwọn èrò náà, ó sọ pé: “Ọwọ́ mi mọ́ kúrò nínú ẹ̀jẹ̀ ọkùnrin yìí. Ẹ̀yin fúnra yín ni kí ẹ lọ wá nǹkan ṣe sí i.”
-
-
-