2 “Tí nǹkan kan bá lé sí ara* ẹnì kan, tó sé èépá tàbí tí awọ ara rẹ̀ yọ àbààwọ́n, tó sì lè yọrí sí àrùn ẹ̀tẹ̀*+ ní awọ ara rẹ̀, kí wọ́n mú un wá sọ́dọ̀ àlùfáà Áárónì tàbí ọ̀kan lára àwọn ọmọ rẹ̀ tó jẹ́ àlùfáà.+
44 ó sọ fún un pé: “Rí i pé o ò sọ nǹkan kan fún ẹnikẹ́ni, àmọ́ lọ fi ara rẹ han àlùfáà, kí o sì mú àwọn ohun tí Mósè sọ dání láti wẹ̀ ọ́ mọ́,+ kó lè jẹ́ ẹ̀rí fún wọn.”+