8 Jèhófà tún sọ fún Áárónì pé: “Èmi fúnra mi fi gbogbo ọrẹ tí wọ́n bá ṣe fún mi+ sí ìkáwọ́ rẹ. Mo ti fún ìwọ àti àwọn ọmọ rẹ lára gbogbo ohun mímọ́ tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì bá fi ṣe ọrẹ, kó jẹ́ ìpín+ yín títí lọ.
5 Gbàrà tí ọba pa àṣẹ náà, àwọn ọmọ Ísírẹ́lì mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àkọ́so ọkà, wáìnì tuntun, òróró+ àti oyin pẹ̀lú gbogbo irè oko wá;+ wọ́n mú ìdá mẹ́wàá ohun gbogbo wá ní ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ.+