19 Jèhófà, jọ̀ọ́ tẹ́tí gbọ́. Jèhófà, jọ̀ọ́ dárí jì.+ Jèhófà, jọ̀ọ́ fiyè sí wa, kí o sì gbé ìgbésẹ̀! Má ṣe jẹ́ kó pẹ́, torí tìẹ, Ọlọ́run mi, torí orúkọ rẹ la fi pe ìlú rẹ àti àwọn èèyàn rẹ.”+
17 kí àwọn tó ṣẹ́ kù lè máa wá Jèhófà* taratara, àwọn àti àwọn èèyàn gbogbo orílẹ̀-èdè, àwọn tí à ń fi orúkọ mi pè, ni Jèhófà* ẹni tó ń ṣe àwọn nǹkan yìí wí,+