Émọ́sì 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 ‘Mo fi ooru tó ń jóni àti èbíbu* kọ lù yín.+ Ẹ̀ ń mú kí àwọn ọgbà yín àti oko àjàrà yín di púpọ̀,+Ṣùgbọ́n eéṣú ló jẹ igi ọ̀pọ̀tọ́ yín àti igi ólífì yín run;Síbẹ̀, ẹ kò pa dà sọ́dọ̀ mi,’+ ni Jèhófà wí.
9 ‘Mo fi ooru tó ń jóni àti èbíbu* kọ lù yín.+ Ẹ̀ ń mú kí àwọn ọgbà yín àti oko àjàrà yín di púpọ̀,+Ṣùgbọ́n eéṣú ló jẹ igi ọ̀pọ̀tọ́ yín àti igi ólífì yín run;Síbẹ̀, ẹ kò pa dà sọ́dọ̀ mi,’+ ni Jèhófà wí.