Hébérù 12:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ẹ kíyè sára gidigidi ká má bàa rí ẹnikẹ́ni tí kò ní gba inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run, kí gbòǹgbò kankan tó ní májèlé má bàa rú yọ láti dá wàhálà sílẹ̀, kó sì sọ ọ̀pọ̀ di aláìmọ́;+
15 Ẹ kíyè sára gidigidi ká má bàa rí ẹnikẹ́ni tí kò ní gba inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run, kí gbòǹgbò kankan tó ní májèlé má bàa rú yọ láti dá wàhálà sílẹ̀, kó sì sọ ọ̀pọ̀ di aláìmọ́;+