22 Àwọn ọgọ́rùn-ún mẹ́ta (300) ọkùnrin tó ń fun ìwo náà ò dáwọ́ dúró, Jèhófà sì mú kí àwọn ọmọ ogun dojú idà kọra wọn ní gbogbo ibùdó náà;+ àwọn ọmọ ogun náà sì sá lọ títí dé Bẹti-ṣítà, wọ́n sá dé Sérérà, títí dé ẹ̀yìn ìlú Ebẹli-méhólà+ lẹ́gbẹ̀ẹ́ Tábátì.