Nọ́ńbà 21:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Bí Ísírẹ́lì ṣe gba gbogbo àwọn ìlú yìí nìyẹn, wọ́n wá ń gbé ní gbogbo ìlú àwọn Ámórì,+ ní Hẹ́ṣíbónì àti gbogbo àrọko rẹ̀.*
25 Bí Ísírẹ́lì ṣe gba gbogbo àwọn ìlú yìí nìyẹn, wọ́n wá ń gbé ní gbogbo ìlú àwọn Ámórì,+ ní Hẹ́ṣíbónì àti gbogbo àrọko rẹ̀.*