2 Síhónì+ ọba àwọn Ámórì, tó ń gbé ní Hẹ́ṣíbónì, tó sì ń jọba láti Áróérì,+ tó wà létí Àfonífojì Áánónì+ àti láti àárín àfonífojì náà àti ìdajì Gílíádì títí dé Àfonífojì Jábókù, ààlà àwọn ọmọ Ámónì.
13 Ọba àwọn ọmọ Ámónì sọ fún àwọn tí Jẹ́fútà rán wá pé: “Torí pé nígbà tí Ísírẹ́lì kúrò ní Íjíbítì,+ wọ́n gba ilẹ̀ mi láti Áánónì+ dé Jábókù títí dé Jọ́dánì.+ Ó yá, dá a pa dà ní àlàáfíà.”