Nọ́ńbà 32:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Àwọn ọmọ Gádì kọ́* Díbónì,+ Átárótì,+ Áróérì,+ Nọ́ńbà 32:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Bẹti-nímírà+ àti Bẹti-háránì,+ àwọn ìlú olódi, wọ́n sì fi òkúta kọ́ ilé fún àwọn agbo ẹran.