-
1 Kíróníkà 6:77Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
77 Látinú ẹ̀yà Sébúlúnì,+ wọ́n fún àwọn ọmọ Mérárì tó ṣẹ́ kù ní Rímónò pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀ àti Tábórì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀;
-
-
1 Kíróníkà 6:80Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
80 látinú ẹ̀yà Gádì, Rámótì ní Gílíádì pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀, Máhánáímù+ pẹ̀lú àwọn ibi ìjẹko rẹ̀,
-