Jóṣúà 7:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Wọ́n kó òkúta jọ pelemọ lé e lórí, ó sì wà bẹ́ẹ̀ títí dòní. Bí inú tó ń bí Jèhófà gidigidi ṣe rọlẹ̀ nìyẹn.+ Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi ń pe ibẹ̀ ní Àfonífojì Ákórì* títí dòní.
26 Wọ́n kó òkúta jọ pelemọ lé e lórí, ó sì wà bẹ́ẹ̀ títí dòní. Bí inú tó ń bí Jèhófà gidigidi ṣe rọlẹ̀ nìyẹn.+ Ìdí nìyẹn tí wọ́n fi ń pe ibẹ̀ ní Àfonífojì Ákórì* títí dòní.