Jóṣúà 18:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Kèké mú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì ní ìdílé-ìdílé, ilẹ̀ tí wọ́n sì fi kèké pín fún wọn wà láàárín àwọn èèyàn Júdà+ àtàwọn èèyàn Jósẹ́fù.+ Jóṣúà 18:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ààlà náà tún lọ láti ibẹ̀ dé Lúsì, ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ tó wà lápá gúúsù Lúsì, ìyẹn Bẹ́tẹ́lì;+ ààlà náà dé Ataroti-ádárì+ lórí òkè tó wà ní gúúsù Bẹti-hórónì Ìsàlẹ̀.+
11 Kèké mú ẹ̀yà Bẹ́ńjámínì ní ìdílé-ìdílé, ilẹ̀ tí wọ́n sì fi kèké pín fún wọn wà láàárín àwọn èèyàn Júdà+ àtàwọn èèyàn Jósẹ́fù.+
13 Ààlà náà tún lọ láti ibẹ̀ dé Lúsì, ní gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ tó wà lápá gúúsù Lúsì, ìyẹn Bẹ́tẹ́lì;+ ààlà náà dé Ataroti-ádárì+ lórí òkè tó wà ní gúúsù Bẹti-hórónì Ìsàlẹ̀.+