Jóṣúà 7:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jóṣúà wá rán àwọn ọkùnrin jáde láti Jẹ́rìkò lọ sí Áì,+ tó wà nítòsí Bẹti-áfénì, ní ìlà oòrùn Bẹ́tẹ́lì,+ ó sọ fún wọn pé: “Ẹ gòkè lọ ṣe amí ilẹ̀ náà.” Àwọn ọkùnrin náà sì lọ ṣe amí ìlú Áì.
2 Jóṣúà wá rán àwọn ọkùnrin jáde láti Jẹ́rìkò lọ sí Áì,+ tó wà nítòsí Bẹti-áfénì, ní ìlà oòrùn Bẹ́tẹ́lì,+ ó sọ fún wọn pé: “Ẹ gòkè lọ ṣe amí ilẹ̀ náà.” Àwọn ọkùnrin náà sì lọ ṣe amí ìlú Áì.