Jóṣúà 15:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ààlà náà lọ dé Bẹti-hógílà,+ ó sì kọjá lọ lápá àríwá Bẹti-árábà,+ ààlà náà sì dé ibi òkúta Bóhánì+ ọmọ Rúbẹ́nì. Jóṣúà 15:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ààlà náà lápá ìwọ̀ oòrùn ni Òkun Ńlá*+ àti èbúté rẹ̀. Èyí ni ààlà àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà ní ìdílé-ìdílé yí ká.
6 Ààlà náà lọ dé Bẹti-hógílà,+ ó sì kọjá lọ lápá àríwá Bẹti-árábà,+ ààlà náà sì dé ibi òkúta Bóhánì+ ọmọ Rúbẹ́nì.
12 Ààlà náà lápá ìwọ̀ oòrùn ni Òkun Ńlá*+ àti èbúté rẹ̀. Èyí ni ààlà àwọn àtọmọdọ́mọ Júdà ní ìdílé-ìdílé yí ká.