Àwọn Onídàájọ́ 1:35 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 35 Torí náà, àwọn Ámórì ṣì ń gbé ní Òkè Hérésì, Áíjálónì+ àti Ṣáálíbímù.+ Àmọ́ nígbà tí agbára* ilé Jósẹ́fù pọ̀ sí i,* wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í fipá kó wọn ṣiṣẹ́ àṣekára.
35 Torí náà, àwọn Ámórì ṣì ń gbé ní Òkè Hérésì, Áíjálónì+ àti Ṣáálíbímù.+ Àmọ́ nígbà tí agbára* ilé Jósẹ́fù pọ̀ sí i,* wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí í fipá kó wọn ṣiṣẹ́ àṣekára.