Jóṣúà 3:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àwọn àlùfáà tó gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà dúró sójú kan lórí ilẹ̀+ ní àárín Jọ́dánì, nígbà tí gbogbo Ísírẹ́lì ń gba orí ilẹ̀ kọjá,+ wọ́n dúró títí gbogbo orílẹ̀-èdè náà fi sọdá Jọ́dánì tán. Sáàmù 66:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ó sọ òkun di ilẹ̀ gbígbẹ;+Wọ́n fi ẹsẹ̀ la odò kọjá.+ Níbẹ̀, à ń yọ̀ nítorí ohun tó ṣe.+
17 Àwọn àlùfáà tó gbé àpótí májẹ̀mú Jèhófà dúró sójú kan lórí ilẹ̀+ ní àárín Jọ́dánì, nígbà tí gbogbo Ísírẹ́lì ń gba orí ilẹ̀ kọjá,+ wọ́n dúró títí gbogbo orílẹ̀-èdè náà fi sọdá Jọ́dánì tán.