Jẹ́nẹ́sísì 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jèhófà sì sọ fún Ábúrámù pé: “Kúrò ní ilẹ̀ rẹ, kí o kúrò lọ́dọ̀ àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ àti ilé bàbá rẹ, kí o lọ sí ilẹ̀ tí màá fi hàn ọ́.+ Nehemáyà 9:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìwọ ni Jèhófà Ọlọ́run tòótọ́, tó yan Ábúrámù,+ tó mú un jáde kúrò ní Úrì,+ ìlú àwọn ará Kálídíà, tó sì sọ orúkọ rẹ̀ ní Ábúráhámù.+ Ìṣe 7:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Sítéfánù dáhùn pé: “Ẹ̀yin èèyàn, ẹ̀yin ará àti ẹ̀yin bàbá, ẹ fetí sílẹ̀. Ọlọ́run ògo fara han Ábúráhámù baba ńlá wa nígbà tó wà ní Mesopotámíà, kí ó tó máa gbé ní Háránì,+
12 Jèhófà sì sọ fún Ábúrámù pé: “Kúrò ní ilẹ̀ rẹ, kí o kúrò lọ́dọ̀ àwọn mọ̀lẹ́bí rẹ àti ilé bàbá rẹ, kí o lọ sí ilẹ̀ tí màá fi hàn ọ́.+
7 Ìwọ ni Jèhófà Ọlọ́run tòótọ́, tó yan Ábúrámù,+ tó mú un jáde kúrò ní Úrì,+ ìlú àwọn ará Kálídíà, tó sì sọ orúkọ rẹ̀ ní Ábúráhámù.+
2 Sítéfánù dáhùn pé: “Ẹ̀yin èèyàn, ẹ̀yin ará àti ẹ̀yin bàbá, ẹ fetí sílẹ̀. Ọlọ́run ògo fara han Ábúráhámù baba ńlá wa nígbà tó wà ní Mesopotámíà, kí ó tó máa gbé ní Háránì,+