Àwọn Onídàájọ́ 4:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Bárákì lé àwọn kẹ̀kẹ́ ogun náà àti àwọn ọmọ ogun títí dé Háróṣétì ti àwọn orílẹ̀-èdè. Bí wọ́n ṣe fi idà pa gbogbo àwọn ọmọ ogun Sísérà nìyẹn; ìkankan nínú wọn ò ṣẹ́ kù.+
16 Bárákì lé àwọn kẹ̀kẹ́ ogun náà àti àwọn ọmọ ogun títí dé Háróṣétì ti àwọn orílẹ̀-èdè. Bí wọ́n ṣe fi idà pa gbogbo àwọn ọmọ ogun Sísérà nìyẹn; ìkankan nínú wọn ò ṣẹ́ kù.+