Àwọn Onídàájọ́ 4:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́ Sísérà sá lọ sí àgọ́ Jáẹ́lì+ ìyàwó Hébà+ ará Kénì, torí àlàáfíà wà láàárín Jábínì+ ọba Hásórì àti ìdílé Hébà ará Kénì.
17 Àmọ́ Sísérà sá lọ sí àgọ́ Jáẹ́lì+ ìyàwó Hébà+ ará Kénì, torí àlàáfíà wà láàárín Jábínì+ ọba Hásórì àti ìdílé Hébà ará Kénì.