Àwọn Onídàájọ́ 4:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Abẹ́ igi ọ̀pẹ Dèbórà ló máa ń jókòó sí, láàárín Rámà+ àti Bẹ́tẹ́lì,+ ní agbègbè olókè Éfúrémù; àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa ń kó ẹjọ́ wọn lọ bá a.
5 Abẹ́ igi ọ̀pẹ Dèbórà ló máa ń jókòó sí, láàárín Rámà+ àti Bẹ́tẹ́lì,+ ní agbègbè olókè Éfúrémù; àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa ń kó ẹjọ́ wọn lọ bá a.