Àwọn Onídàájọ́ 3:10, 11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ẹ̀mí Jèhófà bà lé e,+ ó sì di onídàájọ́ Ísírẹ́lì. Nígbà tó lọ jagun, Jèhófà fi Kuṣani-ríṣátáímù ọba Mesopotámíà* lé e lọ́wọ́, ó sì ṣẹ́gun Kuṣani-ríṣátáímù. 11 Àlàáfíà wá wà ní ilẹ̀ náà* fún ogójì (40) ọdún. Lẹ́yìn náà, Ótíníẹ́lì ọmọ Kénásì wá kú. Àwọn Onídàájọ́ 3:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ọjọ́ yẹn ni Ísírẹ́lì ṣẹ́gun Móábù; àlàáfíà wá wà ní ilẹ̀ náà* fún ọgọ́rin (80) ọdún.+
10 Ẹ̀mí Jèhófà bà lé e,+ ó sì di onídàájọ́ Ísírẹ́lì. Nígbà tó lọ jagun, Jèhófà fi Kuṣani-ríṣátáímù ọba Mesopotámíà* lé e lọ́wọ́, ó sì ṣẹ́gun Kuṣani-ríṣátáímù. 11 Àlàáfíà wá wà ní ilẹ̀ náà* fún ogójì (40) ọdún. Lẹ́yìn náà, Ótíníẹ́lì ọmọ Kénásì wá kú.