-
Ẹ́kísódù 20:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 “Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run rẹ, ẹni tó mú ọ kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì, kúrò ní ilé ẹrú.+
-
-
Léfítíkù 26:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín, tó mú yín kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì, kí ẹ má bàa ṣe ẹrú wọn mọ́. Mo ṣẹ́ àwọn ọ̀pá àjàgà yín, mo sì mú kí ẹ lè nàró ṣánṣán bí ẹ ṣe ń rìn.*
-