Àwọn Onídàájọ́ 11:30, 31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Jẹ́fútà wá jẹ́ ẹ̀jẹ́+ kan fún Jèhófà, ó ní: “Tí o bá fi àwọn ọmọ Ámónì lé mi lọ́wọ́, 31 tí mo bá pa dà ní àlàáfíà látọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Ámónì, ẹnikẹ́ni tó bá jáde ní ẹnu ọ̀nà ilé mi wá pàdé mi máa di ti Jèhófà,+ màá sì fi onítọ̀hún rú ẹbọ sísun.”+
30 Jẹ́fútà wá jẹ́ ẹ̀jẹ́+ kan fún Jèhófà, ó ní: “Tí o bá fi àwọn ọmọ Ámónì lé mi lọ́wọ́, 31 tí mo bá pa dà ní àlàáfíà látọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Ámónì, ẹnikẹ́ni tó bá jáde ní ẹnu ọ̀nà ilé mi wá pàdé mi máa di ti Jèhófà,+ màá sì fi onítọ̀hún rú ẹbọ sísun.”+