-
Àwọn Onídàájọ́ 16:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Sámúsìn sọ fún un pé: “Tí wọ́n bá fi okùn tútù méje tí wọ́n ń so mọ́ ọrun* dè mí, mi ò ní lágbára mọ́, mi ò sì ní yàtọ̀ sí àwọn ọkùnrin yòókù.”
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 16:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ló bá sọ fún obìnrin náà pé: “Tí wọ́n bá fi okùn tuntun tí wọn ò tíì fi ṣiṣẹ́ rí dè mí, mi ò ní lágbára mọ́, mi ò sì ní yàtọ̀ sí àwọn ọkùnrin yòókù.”
-
-
Àwọn Onídàájọ́ 16:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Lẹ́yìn náà, Dẹ̀lílà sọ fún Sámúsìn pé: “O ṣì ń tàn mí títí di báyìí, o sì ń parọ́ fún mi.+ Sọ ohun tí èèyàn lè fi dè ọ́ fún mi.” Ló bá sọ fún obìnrin náà pé: “Tí o bá fi òwú tí wọ́n fi ń hun aṣọ di ìdì-irun méje orí mi.”
-