-
Àwọn Onídàájọ́ 20:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wá gòkè lọ, wọ́n sì sunkún níwájú Jèhófà títí di ìrọ̀lẹ́, wọ́n sì wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà pé: “Ṣé ká tún lọ bá àwọn arákùnrin wa, àwọn èèyàn Bẹ́ńjámínì jà?”+ Jèhófà fèsì pé: “Ẹ lọ bá wọn jà.”
-