-
Rúùtù 2:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Ibi tí wọ́n ti ń kórè ni kí o máa wò, kí o sì máa tẹ̀ lé wọn. Mo ti sọ fún àwọn ọkùnrin tó ń bá mi ṣiṣẹ́ pé wọn kò gbọ́dọ̀ fọwọ́ kàn ọ́.* Tí òùngbẹ bá ń gbẹ ọ́, lọ síbi ìṣà omi, kí o sì mu nínú omi tí àwọn òṣìṣẹ́ mi pọn.”
-