-
Rúùtù 2:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Nígbà tí àkókò oúnjẹ tó, Bóásì sọ fún un pé: “Máa bọ̀ níbí, wá jẹ búrẹ́dì, kí o sì ki èyí tí o bá bù bọ inú ọtí kíkan.” Torí náà, ó jókòó lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn olùkórè. Lẹ́yìn náà, Bóásì fún un ní ọkà yíyan, ó jẹ, ó yó, oúnjẹ rẹ̀ sì ṣẹ́ kù.
-