Àwọn Onídàájọ́ 10:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Wọ́n wá kó àwọn ọlọ́run àjèjì kúrò láàárín wọn, wọ́n sì ń sin Jèhófà,+ débi pé ojú rẹ̀ ò gbà á mọ́* bí Ísírẹ́lì ṣe ń jìyà.+
16 Wọ́n wá kó àwọn ọlọ́run àjèjì kúrò láàárín wọn, wọ́n sì ń sin Jèhófà,+ débi pé ojú rẹ̀ ò gbà á mọ́* bí Ísírẹ́lì ṣe ń jìyà.+