1 Sámúẹ́lì 14:52 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 Ogun tó le ni àwọn Filísínì dojú kọ nígbà ayé Sọ́ọ̀lù.+ Tí Sọ́ọ̀lù bá sì rí ọkùnrin èyíkéyìí tó lágbára tàbí tó láyà, á gbà á síṣẹ́ ogun.+
52 Ogun tó le ni àwọn Filísínì dojú kọ nígbà ayé Sọ́ọ̀lù.+ Tí Sọ́ọ̀lù bá sì rí ọkùnrin èyíkéyìí tó lágbára tàbí tó láyà, á gbà á síṣẹ́ ogun.+