-
2 Sámúẹ́lì 19:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Àmọ́ Dáfídì sọ pé: “Kí ló kàn yín nínú ọ̀rọ̀ yìí, ẹ̀yin ọmọ Seruáyà,+ tí ẹ fi fẹ́ ta kò mí lónìí? Ṣé ó yẹ kí a pa ẹnikẹ́ni ní Ísírẹ́lì lónìí? Ṣé mi ò mọ̀ pé mo ti pa dà di ọba lórí Ísírẹ́lì lónìí?”
-