Jóṣúà 5:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà wá sọ fún Jóṣúà pé: “Mo yí ẹ̀gàn Íjíbítì kúrò lórí yín lónìí.” Wọ́n wá ń pe ibẹ̀ ní Gílígálì*+ títí di òní yìí. 1 Sámúẹ́lì 11:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Lẹ́yìn náà, Sámúẹ́lì sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ wá kí a lọ sí Gílígálì+ láti fìdí ipò ọba náà múlẹ̀.”+
9 Jèhófà wá sọ fún Jóṣúà pé: “Mo yí ẹ̀gàn Íjíbítì kúrò lórí yín lónìí.” Wọ́n wá ń pe ibẹ̀ ní Gílígálì*+ títí di òní yìí.
14 Lẹ́yìn náà, Sámúẹ́lì sọ fún àwọn èèyàn náà pé: “Ẹ wá kí a lọ sí Gílígálì+ láti fìdí ipò ọba náà múlẹ̀.”+