24 Àmọ́, ó ti rẹ àwọn ọkùnrin Ísírẹ́lì tẹnutẹnu ní ọjọ́ yẹn, torí Sọ́ọ̀lù ti mú kí àwọn èèyàn náà búra pé: “Ègún ni fún ẹni tó bá jẹ oúnjẹ kankan kó tó di ìrọ̀lẹ́ àti kó tó di ìgbà tí màá gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá mi!” Torí náà, kò sí ẹnì kankan nínú àwọn èèyàn náà tí ó fi oúnjẹ kan ẹnu.+