1 Sámúẹ́lì 31:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn Filísínì sún mọ́ Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọmọ rẹ̀, àwọn Filísínì sì pa Jónátánì,+ Ábínádábù àti Maliki-ṣúà, àwọn ọmọ Sọ́ọ̀lù.+ 1 Kíróníkà 8:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Nérì+ bí Kíṣì; Kíṣì bí Sọ́ọ̀lù;+ Sọ́ọ̀lù bí Jónátánì,+ Maliki-ṣúà,+ Ábínádábù+ àti Eṣibáálì.*+ 1 Kíróníkà 9:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Nérì+ bí Kíṣì; Kíṣì bí Sọ́ọ̀lù;+ Sọ́ọ̀lù bí Jónátánì,+ Maliki-ṣúà,+ Ábínádábù+ àti Eṣibáálì.
2 Àwọn Filísínì sún mọ́ Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọmọ rẹ̀, àwọn Filísínì sì pa Jónátánì,+ Ábínádábù àti Maliki-ṣúà, àwọn ọmọ Sọ́ọ̀lù.+