11 Torí náà, gbogbo àwọn tó wà ní ẹnubodè ìlú àti àwọn àgbààgbà sọ pé: “Àwa jẹ́rìí sí i! Kí Jèhófà jẹ́ kí ìyàwó tó máa tó wọ ilé rẹ dà bíi Réṣẹ́lì àti Líà, àwọn méjì tó kọ́ ilé Ísírẹ́lì.+ Kí nǹkan máa lọ dáadáa fún ọ ní Éfúrátà,+ kí o sì ní orúkọ rere ní Bẹ́tílẹ́hẹ́mù.+