1 Sámúẹ́lì 21:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àlùfáà náà bá sọ pé: “Idà Gòláyátì+ ará Filísínì tí o pa ní Àfonífojì* Élà+ wà níbí, òun ni wọ́n faṣọ wé lẹ́yìn éfódì+ yẹn. Tí o bá fẹ́ mú un, o lè mú un, torí òun nìkan ló wà níbí.” Dáfídì wá sọ pé: “Kò sí èyí tó dà bíi rẹ̀. Mú un fún mi.”
9 Àlùfáà náà bá sọ pé: “Idà Gòláyátì+ ará Filísínì tí o pa ní Àfonífojì* Élà+ wà níbí, òun ni wọ́n faṣọ wé lẹ́yìn éfódì+ yẹn. Tí o bá fẹ́ mú un, o lè mú un, torí òun nìkan ló wà níbí.” Dáfídì wá sọ pé: “Kò sí èyí tó dà bíi rẹ̀. Mú un fún mi.”