-
Ẹ́kísódù 23:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “Ẹ̀ẹ̀mẹta lọ́dún ni kí ẹ máa ṣe àjọyọ̀ fún mi.+
-
-
1 Sámúẹ́lì 1:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Nígbà tó yá, Ẹlikénà àti gbogbo agbo ilé rẹ̀ lọ láti rú ẹbọ ọdọọdún sí Jèhófà,+ kí ó sì mú ọrẹ tí ó jẹ́jẹ̀ẹ́ wá.
-