1 Sámúẹ́lì 18:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Torí náà, Sọ́ọ̀lù sọ pé: “Màá fi fún un kó lè di ìdẹkùn fún un, kí ọwọ́ àwọn Filísínì lè tẹ̀ ẹ́.”+ Sọ́ọ̀lù bá sọ fún Dáfídì lẹ́ẹ̀kejì pé: “Wàá di àna* mi lónìí yìí.”
21 Torí náà, Sọ́ọ̀lù sọ pé: “Màá fi fún un kó lè di ìdẹkùn fún un, kí ọwọ́ àwọn Filísínì lè tẹ̀ ẹ́.”+ Sọ́ọ̀lù bá sọ fún Dáfídì lẹ́ẹ̀kejì pé: “Wàá di àna* mi lónìí yìí.”