1 Sámúẹ́lì 16:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Àmọ́ ní ti Sọ́ọ̀lù, ẹ̀mí Jèhófà ti kúrò lára rẹ̀,+ Jèhófà sì jẹ́ kí ẹ̀mí búburú máa dà á láàmú.+