1 Sámúẹ́lì 27:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Àmọ́ Dáfídì sọ nínú ọkàn rẹ̀ pé: “Lọ́jọ́ kan, Sọ́ọ̀lù máa pa mí. Ohun tó máa dáa jù ni pé kí n sá lọ+ sí ilẹ̀ àwọn Filísínì; ìgbà yẹn ni Sọ́ọ̀lù á jáwọ́ nínú wíwá mi kiri ní gbogbo ìpínlẹ̀ Ísírẹ́lì,+ màá sì bọ́ lọ́wọ́ rẹ̀.”
27 Àmọ́ Dáfídì sọ nínú ọkàn rẹ̀ pé: “Lọ́jọ́ kan, Sọ́ọ̀lù máa pa mí. Ohun tó máa dáa jù ni pé kí n sá lọ+ sí ilẹ̀ àwọn Filísínì; ìgbà yẹn ni Sọ́ọ̀lù á jáwọ́ nínú wíwá mi kiri ní gbogbo ìpínlẹ̀ Ísírẹ́lì,+ màá sì bọ́ lọ́wọ́ rẹ̀.”