21Nígbà tó yá, Dáfídì wá sọ́dọ̀ àlùfáà Áhímélékì ní Nóbù.+ Jìnnìjìnnì bá Áhímélékì nígbà tó pàdé Dáfídì, ó sì sọ fún un pé: “Kí ló dé tí o fi dá wá, tí kò sẹ́ni tó tẹ̀ lé ọ?”+
7 Ọ̀kan lára àwọn ìránṣẹ́ Sọ́ọ̀lù wà níbẹ̀ lọ́jọ́ yẹn, tí a dá dúró níwájú Jèhófà. Dóẹ́gì+ ni orúkọ rẹ̀, ará Édómù+ ni, òun sì ni olórí àwọn olùṣọ́ àgùntàn Sọ́ọ̀lù.