-
Jóṣúà 15:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Èyí ni ogún ẹ̀yà Júdà ní ìdílé-ìdílé.
-
-
1 Sámúẹ́lì 25:2, 3Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ọkùnrin kan wà ní Máónì+ tó ń ṣiṣẹ́ ní Kámẹ́lì.*+ Ọkùnrin náà ní ọrọ̀ gan-an; ó ní ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) àgùntàn àti ẹgbẹ̀rún kan (1,000) ewúrẹ́, ó sì ń rẹ́ irun àgùntàn rẹ̀ ní Kámẹ́lì. 3 Orúkọ ọkùnrin náà ni Nábálì,+ ìyàwó rẹ̀ sì ń jẹ́ Ábígẹ́lì.+ Ìyàwó yìí ní òye, ó sì rẹwà, ṣùgbọ́n ọkọ rẹ̀ tó jẹ́ ọmọ Kélẹ́bù+ le, ìwà rẹ̀ sì burú.+
-