3 Dáfídì dúró sọ́dọ̀ Ákíṣì ní Gátì, òun àti àwọn ọkùnrin rẹ̀, kálukú pẹ̀lú agbo ilé rẹ̀. Àwọn ìyàwó Dáfídì méjèèjì sì wà pẹ̀lú rẹ̀, Áhínóámù+ ará Jésírẹ́lì àti Ábígẹ́lì,+ opó Nábálì, ará Kámẹ́lì.
3Àwọn ọmọkùnrin tí wọ́n bí fún Dáfídì ní Hébúrónì+ nìyí: Ámínónì+ àkọ́bí, ìyá rẹ̀ ni Áhínóámù+ ará Jésírẹ́lì; ìkejì ni Dáníẹ́lì, ìyá rẹ̀ ni Ábígẹ́lì+ ará Kámẹ́lì;