1 Sámúẹ́lì 17:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Dáfídì béèrè lọ́wọ́ àwọn ọkùnrin tó dúró nítòsí rẹ̀ pé: “Kí ni wọ́n máa ṣe fún ọkùnrin tó bá mú Filísínì tó wà níbẹ̀ yẹn balẹ̀, tó sì mú ẹ̀gàn kúrò lórí Ísírẹ́lì? Ta tiẹ̀ ni Filísínì aláìdádọ̀dọ́* yìí tí á fi máa pẹ̀gàn ìlà ogun Ọlọ́run alààyè?”+ 2 Sámúẹ́lì 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ẹ má sọ ọ́ ní Gátì;+Ẹ má ṣe kéde rẹ̀ ní àwọn ojú ọ̀nà Áṣíkẹ́lónì,Kí àwọn ọmọbìnrin Filísínì má bàa yọ̀,Kí àwọn ọmọbìnrin àwọn aláìdádọ̀dọ́* má bàa dunnú.
26 Dáfídì béèrè lọ́wọ́ àwọn ọkùnrin tó dúró nítòsí rẹ̀ pé: “Kí ni wọ́n máa ṣe fún ọkùnrin tó bá mú Filísínì tó wà níbẹ̀ yẹn balẹ̀, tó sì mú ẹ̀gàn kúrò lórí Ísírẹ́lì? Ta tiẹ̀ ni Filísínì aláìdádọ̀dọ́* yìí tí á fi máa pẹ̀gàn ìlà ogun Ọlọ́run alààyè?”+
20 Ẹ má sọ ọ́ ní Gátì;+Ẹ má ṣe kéde rẹ̀ ní àwọn ojú ọ̀nà Áṣíkẹ́lónì,Kí àwọn ọmọbìnrin Filísínì má bàa yọ̀,Kí àwọn ọmọbìnrin àwọn aláìdádọ̀dọ́* má bàa dunnú.