Àìsáyà 28:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Torí Jèhófà máa dìde bó ṣe ṣe ní Òkè Pérásímù;Ó máa gbéra sọ bó ṣe ṣe ní àfonífojì* tó wà nítòsí Gíbíónì,+Kó lè ṣe ìṣe rẹ̀, ìṣe rẹ̀ tó ṣàjèjì,Kó sì lè ṣe iṣẹ́ rẹ̀, iṣẹ́ rẹ̀ tó ṣàrà ọ̀tọ̀.+
21 Torí Jèhófà máa dìde bó ṣe ṣe ní Òkè Pérásímù;Ó máa gbéra sọ bó ṣe ṣe ní àfonífojì* tó wà nítòsí Gíbíónì,+Kó lè ṣe ìṣe rẹ̀, ìṣe rẹ̀ tó ṣàjèjì,Kó sì lè ṣe iṣẹ́ rẹ̀, iṣẹ́ rẹ̀ tó ṣàrà ọ̀tọ̀.+