2 Sámúẹ́lì 18:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Áhímáásì+ ọmọ Sádókù sọ pé: “Jọ̀wọ́, jẹ́ kí n sáré lọ ròyìn ohun tó ṣẹlẹ̀ fún ọba, nítorí pé Jèhófà ti bá a dá ẹjọ́ rẹ̀ lọ́nà tó tọ́ bí ó ṣe gbà á lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá rẹ̀.”+
19 Áhímáásì+ ọmọ Sádókù sọ pé: “Jọ̀wọ́, jẹ́ kí n sáré lọ ròyìn ohun tó ṣẹlẹ̀ fún ọba, nítorí pé Jèhófà ti bá a dá ẹjọ́ rẹ̀ lọ́nà tó tọ́ bí ó ṣe gbà á lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá rẹ̀.”+