2 Sámúẹ́lì 16:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Nígbà tí Húṣáì+ ará Áríkì,+ ọ̀rẹ́* Dáfídì, wọlé wá sọ́dọ̀ Ábúsálómù, Húṣáì sọ fún Ábúsálómù pé: “Kí ẹ̀mí ọba ó gùn o!+ Kí ẹ̀mí ọba ó gùn o!” 1 Kíróníkà 27:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Áhítófẹ́lì+ jẹ́ agbani-nímọ̀ràn ọba, Húṣáì+ tó jẹ́ Áríkì sì ni ọ̀rẹ́* ọba.
16 Nígbà tí Húṣáì+ ará Áríkì,+ ọ̀rẹ́* Dáfídì, wọlé wá sọ́dọ̀ Ábúsálómù, Húṣáì sọ fún Ábúsálómù pé: “Kí ẹ̀mí ọba ó gùn o!+ Kí ẹ̀mí ọba ó gùn o!”