-
2 Sámúẹ́lì 18:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ọba wá pàṣẹ fún Jóábù àti Ábíṣáì àti Ítáì pé: “Ẹ ṣe ọ̀dọ́kùnrin náà Ábúsálómù jẹ́jẹ́ nítorí mi.”+ Gbogbo àwọn ọkùnrin náà gbọ́ nígbà tí ọba pàṣẹ fún gbogbo àwọn olórí nítorí Ábúsálómù.
-